Òwe 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹni tó ń ṣọ́ ẹnu rẹ̀* ń dáàbò bo ẹ̀mí* rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó ń la ẹnu rẹ̀ gbàgà yóò pa run.+ Òwe 21:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹni tó bá ń ṣọ́ ẹnu àti ahọ́n rẹ̀Ń pa ara* rẹ̀ mọ́ lọ́wọ́ wàhálà.+ Jémíìsì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Tí ẹnikẹ́ni bá rò pé òun ń jọ́sìn Ọlọ́run,* àmọ́ tí kò ṣọ́ ahọ́n rẹ̀ gidigidi,*+ ṣe ló ń tan ọkàn ara rẹ̀ jẹ, asán sì ni ìjọsìn rẹ̀.
26 Tí ẹnikẹ́ni bá rò pé òun ń jọ́sìn Ọlọ́run,* àmọ́ tí kò ṣọ́ ahọ́n rẹ̀ gidigidi,*+ ṣe ló ń tan ọkàn ara rẹ̀ jẹ, asán sì ni ìjọsìn rẹ̀.