Òwe 12:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àníyàn inú ọkàn máa ń mú kó rẹ̀wẹ̀sì,*+Àmọ́ ọ̀rọ̀ rere máa ń mú kó túra ká.+ Òwe 17:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọkàn tó ń yọ̀ jẹ́ oògùn tó dára fún ara,*+Àmọ́ ẹ̀mí tí ìdààmú bá máa ń tánni lókun.*+