Léfítíkù 19:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Kí ẹ máa lo òṣùwọ̀n tó péye, ìwọ̀n tó péye, òṣùwọ̀n tó péye fún ohun tí kò lómi* àti òṣùwọ̀n tó péye fún nǹkan olómi.*+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, ẹni tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. Òwe 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Òṣùwọ̀n èké* jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,Àmọ́ ìwọ̀n* tí ó pé máa ń mú inú rẹ̀ dùn.+
36 Kí ẹ máa lo òṣùwọ̀n tó péye, ìwọ̀n tó péye, òṣùwọ̀n tó péye fún ohun tí kò lómi* àti òṣùwọ̀n tó péye fún nǹkan olómi.*+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, ẹni tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.