Òwe 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+
9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+