Òwe 16:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Oníwàhálà* máa ń dá ìyapa sílẹ̀,+Abanijẹ́ sì máa ń tú àwọn ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ká.+