Sáàmù 18:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìwọ jẹ́ mímọ́ sí ẹni tí ó mọ́,+Àmọ́ ìwọ ń jẹ́ kí àwọn oníbékebèke mọ̀ pé òmùgọ̀ ni wọ́n.+ Òwe 6:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Pẹ̀lú ọkàn burúkú,Ó ń gbèrò ibi ní gbogbo ìgbà,+ ó sì ń dá awuyewuye sílẹ̀.+ 15 Torí náà, àjálù rẹ̀ yóò dé lójijì;Ojú ẹsẹ̀ ni yóò wó lulẹ̀, kò sì ní ṣeé wò sàn.+
14 Pẹ̀lú ọkàn burúkú,Ó ń gbèrò ibi ní gbogbo ìgbà,+ ó sì ń dá awuyewuye sílẹ̀.+ 15 Torí náà, àjálù rẹ̀ yóò dé lójijì;Ojú ẹsẹ̀ ni yóò wó lulẹ̀, kò sì ní ṣeé wò sàn.+