-
Jẹ́nẹ́sísì 50:19-21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Jósẹ́fù sọ fún wọn pé: “Ẹ má bẹ̀rù. Ṣé èmi ni Ọlọ́run ni? 20 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé èrò ibi lẹ ní sí mi,+ Ọlọ́run mú kó yọrí sí rere, kó lè dá ẹ̀mí ọ̀pọ̀ èèyàn sí, bó ti ń ṣe lónìí.+ 21 Torí náà, ẹ má bẹ̀rù. Màá ṣì máa pèsè oúnjẹ+ fún ẹ̀yin àti àwọn ọmọ yín kéékèèké.” Bó ṣe tù wọ́n nínú nìyẹn, ó sì fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀.
-