Sáàmù 37:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+ 26 Ó máa ń yáni ní nǹkan látọkàn wá,+Ìbùkún sì ń dúró de àwọn ọmọ rẹ̀.
25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+ 26 Ó máa ń yáni ní nǹkan látọkàn wá,+Ìbùkún sì ń dúró de àwọn ọmọ rẹ̀.