Àìsáyà 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà títí láé,+Torí pé Àpáta ayérayé ni Jáà* Jèhófà.+ Jeremáyà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbùkún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,Ẹni tó fi Jèhófà ṣe ìgbọ́kànlé rẹ̀.+