Sáàmù 101:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní àràárọ̀, màá pa gbogbo àwọn ẹni burúkú ayé lẹ́nu mọ́,*Láti mú gbogbo àwọn aṣebi kúrò ní ìlú Jèhófà.+
8 Ní àràárọ̀, màá pa gbogbo àwọn ẹni burúkú ayé lẹ́nu mọ́,*Láti mú gbogbo àwọn aṣebi kúrò ní ìlú Jèhófà.+