Oníwàásù 7:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọgbọ́n máa ń mú kí ọlọ́gbọ́n lágbára ju akíkanjú ọkùnrin mẹ́wàá tó ń ṣọ́ ìlú.+ 2 Kọ́ríńtì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí àwọn ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara,+ àmọ́ Ọlọ́run ti mú kí wọ́n lágbára+ láti borí àwọn nǹkan tó ti fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in.
4 Nítorí àwọn ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara,+ àmọ́ Ọlọ́run ti mú kí wọ́n lágbára+ láti borí àwọn nǹkan tó ti fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in.