ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 20:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ó sọ pé: “Ẹ fetí sílẹ̀, gbogbo Júdà àti ẹ̀yin tó ń gbé Jerúsálẹ́mù àti Ọba Jèhóṣáfátì! Ohun tí Jèhófà sọ fún yín nìyí, ‘Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn yìí, torí ìjà náà kì í ṣe tiyín, ti Ọlọ́run ni.+

  • 2 Kíróníkà 20:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Kò ní sídìí fún yín láti ja ogun yìí. Ẹ dúró sáyè yín, ẹ dúró jẹ́ẹ́,+ kí ẹ sì rí ìgbàlà Jèhófà lórí yín.*+ Ìwọ Júdà àti Jerúsálẹ́mù, ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà.+ Ní ọ̀la, ẹ jáde sí wọn, Jèhófà á sì wà pẹ̀lú yín.’”+

  • Sáàmù 68:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ọlọ́run tòótọ́ ni Ọlọ́run tó ń gbà wá là;+

      Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì ń gbani lọ́wọ́ ikú.+

  • Ìfihàn 7:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Wọ́n ń ké jáde pé: “Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wa tó jókòó sórí ìtẹ́+ àti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ni ìgbàlà wa ti wá.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́