Sáàmù 37:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Máa fiyè sí aláìlẹ́bi,*Kí o sì máa wo adúróṣinṣin,+Nítorí àlàáfíà ń dúró de ẹni yẹn ní ọjọ́ ọ̀la.+ Òwe 24:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lọ́nà kan náà, mọ̀ pé ọgbọ́n dára fún ọ.*+ Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dáraÌrètí rẹ kò sì ní pa rẹ́.+
37 Máa fiyè sí aláìlẹ́bi,*Kí o sì máa wo adúróṣinṣin,+Nítorí àlàáfíà ń dúró de ẹni yẹn ní ọjọ́ ọ̀la.+
14 Lọ́nà kan náà, mọ̀ pé ọgbọ́n dára fún ọ.*+ Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dáraÌrètí rẹ kò sì ní pa rẹ́.+