Jóòbù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọkùnrin kan wà ní ilẹ̀ Úsì tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jóòbù.*+ Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni; ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.+
1 Ọkùnrin kan wà ní ilẹ̀ Úsì tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jóòbù.*+ Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni; ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.+