Òwe 6:12-14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìkà àti aláìwúlò ẹ̀dá ń rìn kiri tòun ti èké ọ̀rọ̀;+13 Bó ṣe ń ṣẹ́jú,+ bẹ́ẹ̀ ló ń fi ẹsẹ̀ sọ̀rọ̀, tó sì ń nàka. 14 Pẹ̀lú ọkàn burúkú,Ó ń gbèrò ibi ní gbogbo ìgbà,+ ó sì ń dá awuyewuye sílẹ̀.+
12 Ìkà àti aláìwúlò ẹ̀dá ń rìn kiri tòun ti èké ọ̀rọ̀;+13 Bó ṣe ń ṣẹ́jú,+ bẹ́ẹ̀ ló ń fi ẹsẹ̀ sọ̀rọ̀, tó sì ń nàka. 14 Pẹ̀lú ọkàn burúkú,Ó ń gbèrò ibi ní gbogbo ìgbà,+ ó sì ń dá awuyewuye sílẹ̀.+