ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 20:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ni Sọ́ọ̀lù bá ju ọ̀kọ̀ sí i láti fi gún un,+ Jónátánì sì wá mọ̀ pé bàbá òun ti pinnu láti pa Dáfídì.+

  • Òwe 16:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,

      Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+

  • Òwe 22:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Má ṣe bá onínúfùfù kẹ́gbẹ́,

      Má sì bá ẹni tó máa ń tètè bínú da nǹkan pọ̀,

      25 Kí o má bàa kọ́ àwọn ọ̀nà rẹ̀,

      Kí o sì kó ara* rẹ sínú ìdẹkùn.+

  • Òwe 29:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbogbo bí ọ̀rọ̀ ṣe rí lára* òmùgọ̀ ló máa ń sọ jáde,+

      Àmọ́ ọlọ́gbọ́n máa ń mú sùúrù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́