Òwe 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹni tó ń pa àṣẹ mọ́ ń pa ẹ̀mí* rẹ̀ mọ́;+Ẹni tí kì í kíyè sí ọ̀nà rẹ̀ yóò kú.+ Jòhánù 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Tí ẹ bá mọ àwọn nǹkan yìí, aláyọ̀ ni yín tí ẹ bá ń ṣe wọ́n.+ Jémíìsì 1:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+
25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+