Jòhánù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bákan náà, kò sí èèyàn kankan tó tíì gòkè lọ sọ́run+ àfi ẹni tó sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run,+ ìyẹn Ọmọ èèyàn.
13 Bákan náà, kò sí èèyàn kankan tó tíì gòkè lọ sọ́run+ àfi ẹni tó sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run,+ ìyẹn Ọmọ èèyàn.