Jòhánù 6:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 torí mi ò sọ̀ kalẹ̀ wá láti ọ̀run+ kí n lè ṣe ìfẹ́ ara mi, ṣùgbọ́n láti ṣe ìfẹ́ ẹni tó rán mi.+ Jòhánù 8:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ìsàlẹ̀ ni ẹ̀yin ti wá; èmi wá láti òkè.+ Inú ayé yìí lẹ ti wá; èmi ò wá látinú ayé yìí. Jòhánù 8:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Jésù sọ fún wọn pé: “Tó bá jẹ́ Ọlọ́run ni Baba yín, ẹ máa nífẹ̀ẹ́ mi,+ torí pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni mo ti wá, mo sì wà níbí. Èmi kọ́ ni mo rán ara mi wá, àmọ́ Ẹni yẹn ló rán mi.+
23 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ìsàlẹ̀ ni ẹ̀yin ti wá; èmi wá láti òkè.+ Inú ayé yìí lẹ ti wá; èmi ò wá látinú ayé yìí.
42 Jésù sọ fún wọn pé: “Tó bá jẹ́ Ọlọ́run ni Baba yín, ẹ máa nífẹ̀ẹ́ mi,+ torí pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni mo ti wá, mo sì wà níbí. Èmi kọ́ ni mo rán ara mi wá, àmọ́ Ẹni yẹn ló rán mi.+