Sáàmù 104:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àti wáìnì tó ń mú ọkàn èèyàn yọ̀,+Òróró tó ń mú kí ojú dánÀti oúnjẹ tó ń gbé ẹ̀mí ẹni kíkú ró.+ Mátíù 27:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 wọ́n fún un ní wáìnì tí wọ́n pò mọ́ òróòro* mu;+ àmọ́ nígbà tó tọ́ ọ wò, ó kọ̀ láti mu ún.