Òwe 23:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+ 1 Jòhánù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 torí gbogbo ohun tó wà nínú ayé—ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú+ àti fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn*—kò wá látọ̀dọ̀ Baba, àmọ́ ó wá látọ̀dọ̀ ayé.
4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+
16 torí gbogbo ohun tó wà nínú ayé—ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú+ àti fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn*—kò wá látọ̀dọ̀ Baba, àmọ́ ó wá látọ̀dọ̀ ayé.