Òwe 24:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọmọ mi, bẹ̀rù Jèhófà àti ọba.+ Má sì bá àwọn oníyapa* kẹ́gbẹ́.+ 22 Nítorí àjálù wọn yóò dé lójijì.+ Ta ló mọ ìparun tí àwọn méjèèjì* máa mú bá wọn?+ Róòmù 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí gbogbo èèyàn* máa tẹrí ba fún àwọn aláṣẹ onípò gíga,+ nítorí kò sí àṣẹ kankan àfi èyí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run;+ àwọn aláṣẹ tó wà ni a gbé sí àwọn ipò wọn tó ní ààlà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+ Títù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Máa rán wọn létí pé kí wọ́n máa tẹrí ba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ, kí wọ́n máa ṣègbọràn sí wọn,+ kí wọ́n sì múra tán láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo, 1 Pétérù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ
21 Ọmọ mi, bẹ̀rù Jèhófà àti ọba.+ Má sì bá àwọn oníyapa* kẹ́gbẹ́.+ 22 Nítorí àjálù wọn yóò dé lójijì.+ Ta ló mọ ìparun tí àwọn méjèèjì* máa mú bá wọn?+
13 Kí gbogbo èèyàn* máa tẹrí ba fún àwọn aláṣẹ onípò gíga,+ nítorí kò sí àṣẹ kankan àfi èyí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run;+ àwọn aláṣẹ tó wà ni a gbé sí àwọn ipò wọn tó ní ààlà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+
3 Máa rán wọn létí pé kí wọ́n máa tẹrí ba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ, kí wọ́n máa ṣègbọràn sí wọn,+ kí wọ́n sì múra tán láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo,
13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ