Sáàmù 37:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Láìpẹ́, àwọn ẹni burúkú ò ní sí mọ́;+ Wàá wo ibi tí wọ́n wà tẹ́lẹ̀,Wọn ò ní sí níbẹ̀.+ Àìsáyà 57:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kò sí àlàáfíà fún ẹni burúkú,”+ ni Ọlọ́run mi wí.