Jóòbù 24:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 A gbé wọn ga fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà, wọn ò sí mọ́.+ A rẹ̀ wọ́n sílẹ̀,+ a sì kó wọn jọ bíi gbogbo èèyàn yòókù;A gé wọn kúrò bí orí ọkà.
24 A gbé wọn ga fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà, wọn ò sí mọ́.+ A rẹ̀ wọ́n sílẹ̀,+ a sì kó wọn jọ bíi gbogbo èèyàn yòókù;A gé wọn kúrò bí orí ọkà.