Oníwàásù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+ Oníwàásù 3:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Mo ti wá rí i pé kò sí ohun tó dáa fún wọn ju pé kí wọ́n máa yọ̀ kí wọ́n sì máa ṣe rere nígbà ayé wọn,+ 13 àti pé kí kálukú máa jẹ, kó máa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀. Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni.+
24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+
12 Mo ti wá rí i pé kò sí ohun tó dáa fún wọn ju pé kí wọ́n máa yọ̀ kí wọ́n sì máa ṣe rere nígbà ayé wọn,+ 13 àti pé kí kálukú máa jẹ, kó máa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀. Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni.+