Diutarónómì 33:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn rẹ̀;+Gbogbo ẹni mímọ́ wọn wà ní ọwọ́ rẹ.+ Wọ́n jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ rẹ;+Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ rẹ.+ 1 Sámúẹ́lì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ń dáàbò bo ìṣísẹ̀ àwọn adúróṣinṣin rẹ̀,+Ṣùgbọ́n a ó pa àwọn ẹni burúkú lẹ́nu mọ́ nínú òkùnkùn,+Nítorí kì í ṣe nípa agbára ni èèyàn fi ń borí.+ Sáàmù 37:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Fi ọ̀nà rẹ lé Jèhófà lọ́wọ́;*+Gbẹ́kẹ̀ lé e, yóò sì gbé ìgbésẹ̀ nítorí rẹ.+
3 Ó nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn rẹ̀;+Gbogbo ẹni mímọ́ wọn wà ní ọwọ́ rẹ.+ Wọ́n jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ rẹ;+Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ rẹ.+
9 Ó ń dáàbò bo ìṣísẹ̀ àwọn adúróṣinṣin rẹ̀,+Ṣùgbọ́n a ó pa àwọn ẹni burúkú lẹ́nu mọ́ nínú òkùnkùn,+Nítorí kì í ṣe nípa agbára ni èèyàn fi ń borí.+