Máàkù 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ṣebí káfíńtà yẹn nìyí,+ ọmọ Màríà,+ tó tún jẹ́ arákùnrin Jémíìsì,+ Jósẹ́fù, Júdásì àti Símónì,+ àbí òun kọ́? Àwọn arábìnrin rẹ̀ sì wà níbí pẹ̀lú wa, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?” Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kọsẹ̀ nítorí rẹ̀. 1 Kọ́ríńtì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kò sí ìkankan nínú àwọn alákòóso ètò àwọn nǹkan yìí* tó mọ ọgbọ́n yìí,+ torí ká ní wọ́n mọ̀ ọ́n ni, wọn ì bá má pa Olúwa ológo.*
3 Ṣebí káfíńtà yẹn nìyí,+ ọmọ Màríà,+ tó tún jẹ́ arákùnrin Jémíìsì,+ Jósẹ́fù, Júdásì àti Símónì,+ àbí òun kọ́? Àwọn arábìnrin rẹ̀ sì wà níbí pẹ̀lú wa, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?” Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kọsẹ̀ nítorí rẹ̀.
8 Kò sí ìkankan nínú àwọn alákòóso ètò àwọn nǹkan yìí* tó mọ ọgbọ́n yìí,+ torí ká ní wọ́n mọ̀ ọ́n ni, wọn ì bá má pa Olúwa ológo.*