Àìsáyà 53:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó máa jáde wá bí ẹ̀ka igi+ níwájú rẹ̀,* bíi gbòǹgbò látinú ilẹ̀ tó gbẹ táútáú. Ìrísí rẹ̀ kò buyì kún un, kò sì rẹwà rárá;+Tí a bá sì rí i, ìrísí rẹ̀ kò fà wá sún mọ́ ọn.*
2 Ó máa jáde wá bí ẹ̀ka igi+ níwájú rẹ̀,* bíi gbòǹgbò látinú ilẹ̀ tó gbẹ táútáú. Ìrísí rẹ̀ kò buyì kún un, kò sì rẹwà rárá;+Tí a bá sì rí i, ìrísí rẹ̀ kò fà wá sún mọ́ ọn.*