-
Àìsáyà 52:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Bó ṣe jẹ́ pé ọ̀pọ̀ ló ń wò ó tìyanutìyanu,
Tí wọ́n ba ìrísí rẹ̀ jẹ́ ju ti èèyàn èyíkéyìí míì,
Tí wọ́n sì ba ìrísí rẹ̀ tó buyì kún un jẹ́ ju ti ọmọ aráyé,
-