Àìsáyà 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀ka igi+ kan máa yọ látinú kùkùté Jésè,+Èéhù+ kan látinú gbòǹgbò rẹ̀ sì máa so èso. Sekaráyà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí o sì sọ fún un pé,“‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Èéhù+ rèé. Yóò hù jáde láti àyè rẹ̀, yóò sì kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.+
12 Kí o sì sọ fún un pé,“‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Èéhù+ rèé. Yóò hù jáde láti àyè rẹ̀, yóò sì kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.+