1 Àwọn Ọba 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ni Jésíbẹ́lì bá rán òjíṣẹ́ kan sí Èlíjà pé: “Kí àwọn ọlọ́run fìyà jẹ mí gan-an tí mi ò bá ṣe ọ́ bí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn* ní ìwòyí ọ̀la!” 1 Àwọn Ọba 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó rin ìrìn ọjọ́ kan lọ sínú aginjù, ó dúró, ó jókòó sábẹ́ igi wíwẹ́, ó sì béèrè pé kí òun* kú. Ó sọ pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Jèhófà, gba ẹ̀mí* mi,+ nítorí mi ò sàn ju àwọn baba ńlá mi.” Jeremáyà 20:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí nìdí tí ò kúkú fi pa mí nígbà tí mo wà nínú ikùn,Kí inú ìyá mi lè di ibi ìsìnkú miKí oyún wà nínú ikùn rẹ̀ nígbà gbogbo?+ 18 Kí nìdí tí mo fi jáde kúrò nínú ikùnLáti rí ìdààmú àti ẹ̀dùn ọkàn,Láti mú kí àwọn ọjọ́ mi dópin nínú ìtìjú?+
2 Ni Jésíbẹ́lì bá rán òjíṣẹ́ kan sí Èlíjà pé: “Kí àwọn ọlọ́run fìyà jẹ mí gan-an tí mi ò bá ṣe ọ́ bí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn* ní ìwòyí ọ̀la!”
4 Ó rin ìrìn ọjọ́ kan lọ sínú aginjù, ó dúró, ó jókòó sábẹ́ igi wíwẹ́, ó sì béèrè pé kí òun* kú. Ó sọ pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Jèhófà, gba ẹ̀mí* mi,+ nítorí mi ò sàn ju àwọn baba ńlá mi.”
17 Kí nìdí tí ò kúkú fi pa mí nígbà tí mo wà nínú ikùn,Kí inú ìyá mi lè di ibi ìsìnkú miKí oyún wà nínú ikùn rẹ̀ nígbà gbogbo?+ 18 Kí nìdí tí mo fi jáde kúrò nínú ikùnLáti rí ìdààmú àti ẹ̀dùn ọkàn,Láti mú kí àwọn ọjọ́ mi dópin nínú ìtìjú?+