Jóòbù 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọjọ́ mi ń yára sáré ju ohun èlò tí wọ́n fi ń hun aṣọ,+Wọ́n sì dópin láìnírètí.+ Oníwàásù 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí èèyàn lè fi ọgbọ́n àti ìmọ̀ àti òye ṣiṣẹ́ ní àṣekára, àmọ́ ó gbọ́dọ̀ fi èrè rẹ̀* sílẹ̀ fún ẹni tí kò ṣiṣẹ́ fún un.+ Asán ni èyí pẹ̀lú àti àdánù* ńlá. Róòmù 8:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí a tẹ ìṣẹ̀dá lórí ba fún asán,+ kì í ṣe nípa ìfẹ́ òun fúnra rẹ̀, àmọ́ nípasẹ̀ ẹni tó tẹ̀ ẹ́ lórí ba, nítorí ìrètí,
21 Nítorí èèyàn lè fi ọgbọ́n àti ìmọ̀ àti òye ṣiṣẹ́ ní àṣekára, àmọ́ ó gbọ́dọ̀ fi èrè rẹ̀* sílẹ̀ fún ẹni tí kò ṣiṣẹ́ fún un.+ Asán ni èyí pẹ̀lú àti àdánù* ńlá.
20 Nítorí a tẹ ìṣẹ̀dá lórí ba fún asán,+ kì í ṣe nípa ìfẹ́ òun fúnra rẹ̀, àmọ́ nípasẹ̀ ẹni tó tẹ̀ ẹ́ lórí ba, nítorí ìrètí,