Jẹ́nẹ́sísì 1:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run rí gbogbo ohun tó ti ṣe, sì wò ó! ó dára gan-an.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹfà. Róòmù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí àwọn ànímọ́* rẹ̀ tí kò ṣeé fojú rí ni a rí ní kedere láti ìgbà ìṣẹ̀dá ayé síwájú, torí à ń fi òye mọ̀ wọ́n látinú àwọn ohun tó dá,+ títí kan agbára ayérayé tó ní+ àti bó ṣe jẹ́ Ọlọ́run,+ tó fi jẹ́ pé wọn ò ní àwíjàre.
31 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run rí gbogbo ohun tó ti ṣe, sì wò ó! ó dára gan-an.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹfà.
20 Nítorí àwọn ànímọ́* rẹ̀ tí kò ṣeé fojú rí ni a rí ní kedere láti ìgbà ìṣẹ̀dá ayé síwájú, torí à ń fi òye mọ̀ wọ́n látinú àwọn ohun tó dá,+ títí kan agbára ayérayé tó ní+ àti bó ṣe jẹ́ Ọlọ́run,+ tó fi jẹ́ pé wọn ò ní àwíjàre.