ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 19:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ó sàn kéèyàn jẹ́ aláìní àmọ́ kó máa rìn nínú ìwà títọ́+

      Ju kéèyàn jẹ́ òmùgọ̀ kó sì máa parọ́.+

  • Òwe 28:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Aláìní tó ń rìn nínú ìwà títọ́

      Sàn ju olówó tí ọ̀nà rẹ̀ wọ́ lọ.+

  • Òwe 28:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Aṣáájú tí kò lóye máa ń ṣi agbára lò,+

      Àmọ́ ẹni tó kórìíra èrè tí kò tọ́ yóò mú ẹ̀mí ara rẹ̀ gùn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́