ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 30:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Tí ọkùnrin kan bá jẹ́jẹ̀ẹ́+ fún Jèhófà tàbí tó búra+ pé òun máa* yẹra fún nǹkan kan, kò gbọ́dọ̀ yẹ ọ̀rọ̀ rẹ̀.+ Gbogbo ohun tó jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun máa ṣe ni kó ṣe.+

  • 1 Sámúẹ́lì 14:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àmọ́, ó ti rẹ àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì tẹnutẹnu ní ọjọ́ yẹn, torí Sọ́ọ̀lù ti mú kí àwọn èèyàn náà búra pé: “Ègún ni fún ẹni tó bá jẹ oúnjẹ* kankan kó tó di ìrọ̀lẹ́ àti kó tó di ìgbà tí màá gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi!” Torí náà, kò sí ẹnì kankan nínú àwọn èèyàn náà tí ó fi oúnjẹ kan ẹnu.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́