Jòhánù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ẹni tí ìfẹ́ rẹ̀ ju èyí lọ, pé kí ẹnì kan fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀.+ Éfésù 5:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ máa nífẹ̀ẹ́ àwọn aya yín,+ bí Kristi ṣe nífẹ̀ẹ́ ìjọ, tó sì fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún un,+ Ìfihàn 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Wọ́n ṣẹ́gun rẹ̀ + nítorí ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà àti nítorí ọ̀rọ̀ ìjẹ́rìí wọn,+ wọn ò sì nífẹ̀ẹ́ ọkàn* wọn,+ kódà lójú ikú.
11 Wọ́n ṣẹ́gun rẹ̀ + nítorí ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà àti nítorí ọ̀rọ̀ ìjẹ́rìí wọn,+ wọn ò sì nífẹ̀ẹ́ ọkàn* wọn,+ kódà lójú ikú.