Orin Sólómọ́nì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Wò ó! O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi. Wò ó! O rẹwà gan-an. Ojú rẹ rí bíi ti àdàbà, lábẹ́ aṣọ tí o fi bojú. Irun rẹ dà bí agbo ewúrẹ́Tí wọ́n ń rọ́ bọ̀ láti orí àwọn òkè Gílíádì.+ Orin Sólómọ́nì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mo ti sùn lọ, àmọ́ ọkàn mi ò sùn.+ Mo gbọ́ ìró olólùfẹ́ mi tó ń kan ilẹ̀kùn!” ‘Ṣílẹ̀kùn fún mi, arábìnrin mi, olólùfẹ́ mi,Àdàbà mi, ẹni tí ẹwà rẹ̀ ò lábùlà! Torí ìrì ti sẹ̀ sí mi lórí,Ìrì òru+ ti mú kí irun mi tutù.’
4 “Wò ó! O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi. Wò ó! O rẹwà gan-an. Ojú rẹ rí bíi ti àdàbà, lábẹ́ aṣọ tí o fi bojú. Irun rẹ dà bí agbo ewúrẹ́Tí wọ́n ń rọ́ bọ̀ láti orí àwọn òkè Gílíádì.+
2 “Mo ti sùn lọ, àmọ́ ọkàn mi ò sùn.+ Mo gbọ́ ìró olólùfẹ́ mi tó ń kan ilẹ̀kùn!” ‘Ṣílẹ̀kùn fún mi, arábìnrin mi, olólùfẹ́ mi,Àdàbà mi, ẹni tí ẹwà rẹ̀ ò lábùlà! Torí ìrì ti sẹ̀ sí mi lórí,Ìrì òru+ ti mú kí irun mi tutù.’