-
Òwe 27:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Òróró àti tùràrí máa ń mú ọkàn yọ̀;
Bẹ́ẹ̀ ni adùn ọ̀rẹ́ máa ń wá látinú ìmọ̀ràn àtọkànwá.+
-
-
Orin Sólómọ́nì 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mo dìde kí n lè ṣílẹ̀kùn fún olólùfẹ́ mi;
Òjíá ń kán tótó ní ọwọ́ mi,
Òjíá olómi ń kán ní àwọn ìka mi,
Sára ọwọ́ ilẹ̀kùn.
-