Orin Sólómọ́nì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Ìwọ tí ò ń gbé inú àwọn ọgbà,+Àwọn ọ̀rẹ́ fẹ́ gbọ́ ohùn rẹ. Jẹ́ kí n gbọ́ ọ.”+