Orin Sólómọ́nì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ìwọ àdàbà mi, tí o wà nínú ihò àpáta,+Níbi kọ́lọ́fín òkè tó dà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́,Jẹ́ kí n rí ọ, kí n sì gbọ́ ohùn rẹ,+Torí ohùn rẹ dùn, ìrísí rẹ sì dára gan-an.’”+
14 Ìwọ àdàbà mi, tí o wà nínú ihò àpáta,+Níbi kọ́lọ́fín òkè tó dà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́,Jẹ́ kí n rí ọ, kí n sì gbọ́ ohùn rẹ,+Torí ohùn rẹ dùn, ìrísí rẹ sì dára gan-an.’”+