Oníwàásù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Orúkọ rere* sàn ju òróró dáradára,+ ọjọ́ ikú sì sàn ju ọjọ́ tí a bíni lọ.