Nehemáyà 3:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Lẹ́yìn rẹ̀, Pálálì ọmọ Úṣáì ṣe iṣẹ́ àtúnṣe níwájú Ìtì Ògiri àti ilé gogoro tó yọ jáde láti Ilé Ọba,*+ ti apá òkè tó jẹ́ ti Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+ Lẹ́yìn rẹ̀, ó kan Pedáyà ọmọ Páróṣì.+ Orin Sólómọ́nì 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọrùn rẹ+ dà bí ilé gogoro+ tí wọ́n fi eyín erin kọ́. Ojú rẹ+ dà bí àwọn omi Hẹ́ṣíbónì,+Lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè Bati-rábímù. Imú rẹ dà bí ilé gogoro Lẹ́bánónì,Tó dojú kọ Damásíkù.
25 Lẹ́yìn rẹ̀, Pálálì ọmọ Úṣáì ṣe iṣẹ́ àtúnṣe níwájú Ìtì Ògiri àti ilé gogoro tó yọ jáde láti Ilé Ọba,*+ ti apá òkè tó jẹ́ ti Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+ Lẹ́yìn rẹ̀, ó kan Pedáyà ọmọ Páróṣì.+
4 Ọrùn rẹ+ dà bí ilé gogoro+ tí wọ́n fi eyín erin kọ́. Ojú rẹ+ dà bí àwọn omi Hẹ́ṣíbónì,+Lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè Bati-rábímù. Imú rẹ dà bí ilé gogoro Lẹ́bánónì,Tó dojú kọ Damásíkù.