Orin Sólómọ́nì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Mo ti wọnú ọgbà mi,+Ìwọ arábìnrin mi, ìyàwó mi. Mo ti já òjíá mi àti ewéko olóòórùn dídùn mi.+ Mo ti jẹ afárá oyin mi àti oyin mi;Mo ti mu wáìnì mi àti wàrà mi.”+ “Ẹ jẹun, ẹ̀yin ọ̀rẹ́ ọ̀wọ́n! Ẹ mu ìfẹ́,+ kí ẹ sì yó!”
5 “Mo ti wọnú ọgbà mi,+Ìwọ arábìnrin mi, ìyàwó mi. Mo ti já òjíá mi àti ewéko olóòórùn dídùn mi.+ Mo ti jẹ afárá oyin mi àti oyin mi;Mo ti mu wáìnì mi àti wàrà mi.”+ “Ẹ jẹun, ẹ̀yin ọ̀rẹ́ ọ̀wọ́n! Ẹ mu ìfẹ́,+ kí ẹ sì yó!”