Ẹ́sítà 8:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Módékáì wá jáde níwájú ọba nínú ẹ̀wù oyè olówùú búlúù àti funfun,* ó dé adé ńlá tí wọ́n fi wúrà ṣe, ó sì wọ aṣọ àwọ̀lékè àtàtà olówùú pọ́pù.+ Igbe ayọ̀ sì sọ ní ìlú Ṣúṣánì.*
15 Módékáì wá jáde níwájú ọba nínú ẹ̀wù oyè olówùú búlúù àti funfun,* ó dé adé ńlá tí wọ́n fi wúrà ṣe, ó sì wọ aṣọ àwọ̀lékè àtàtà olówùú pọ́pù.+ Igbe ayọ̀ sì sọ ní ìlú Ṣúṣánì.*