Àìsáyà 44:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Alágbẹ̀dẹ ń fi irinṣẹ́ rẹ̀* lu irin lórí ẹyin iná. Ó ń fi àwọn òòlù ṣe é,Ó ń fi apá rẹ̀ tó lágbára ṣe é.+ Ebi wá ń pa á, okun sì tán nínú rẹ̀;Kò mu omi, ó sì ti rẹ̀ ẹ́. Àìsáyà 46:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn kan wà tó ń kó wúrà jáde yàlàyòlò látinú àpò wọn;Wọ́n ń wọn fàdákà lórí òṣùwọ̀n. Wọ́n gba oníṣẹ́ irin síṣẹ́, ó sì fi ṣe ọlọ́run.+ Wọ́n wá wólẹ̀, àní, wọ́n jọ́sìn rẹ̀.*+
12 Alágbẹ̀dẹ ń fi irinṣẹ́ rẹ̀* lu irin lórí ẹyin iná. Ó ń fi àwọn òòlù ṣe é,Ó ń fi apá rẹ̀ tó lágbára ṣe é.+ Ebi wá ń pa á, okun sì tán nínú rẹ̀;Kò mu omi, ó sì ti rẹ̀ ẹ́.
6 Àwọn kan wà tó ń kó wúrà jáde yàlàyòlò látinú àpò wọn;Wọ́n ń wọn fàdákà lórí òṣùwọ̀n. Wọ́n gba oníṣẹ́ irin síṣẹ́, ó sì fi ṣe ọlọ́run.+ Wọ́n wá wólẹ̀, àní, wọ́n jọ́sìn rẹ̀.*+