Àìsáyà 43:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Nítorí yín, màá ránṣẹ́ sí Bábílónì, màá sì gé gbogbo ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè lulẹ̀,+Àwọn ará Kálídíà sì máa ké jáde nínú ìdààmú, nínú àwọn ọkọ̀ òkun wọn.+ Àìsáyà 47:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ẹni tó ń tún wa rà,Ni Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.”
14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Nítorí yín, màá ránṣẹ́ sí Bábílónì, màá sì gé gbogbo ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè lulẹ̀,+Àwọn ará Kálídíà sì máa ké jáde nínú ìdààmú, nínú àwọn ọkọ̀ òkun wọn.+