Diutarónómì 28:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Jèhófà máa mú kí àwọn ọ̀tá rẹ dìde sí ọ, o sì máa sìn+ wọ́n tòun ti ebi+ àti òùngbẹ, láìsí aṣọ gidi lọ́rùn rẹ àti láìní ohunkóhun. Ó máa fi àjàgà irin sí ọ lọ́rùn títí ó fi máa pa ọ́ run. Émọ́sì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí,‘Nígbà tí màá rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,Kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí ti omi,Bí kò ṣe ti gbígbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà.+
48 Jèhófà máa mú kí àwọn ọ̀tá rẹ dìde sí ọ, o sì máa sìn+ wọ́n tòun ti ebi+ àti òùngbẹ, láìsí aṣọ gidi lọ́rùn rẹ àti láìní ohunkóhun. Ó máa fi àjàgà irin sí ọ lọ́rùn títí ó fi máa pa ọ́ run.
11 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí,‘Nígbà tí màá rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,Kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí ti omi,Bí kò ṣe ti gbígbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà.+