Àìsáyà 46:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá pe ẹyẹ aṣọdẹ wá láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+Ọkùnrin tó máa ṣe ohun tí mo pinnu*+ máa wá láti ilẹ̀ tó jìn. Mo ti sọ̀rọ̀, màá sì mú kó ṣẹ. Mo ti ní in lọ́kàn, màá sì ṣe é.+ Ìfihàn 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìkẹfà da ohun tó wà nínú abọ́ rẹ̀ sínú odò ńlá Yúfírétì,+ omi rẹ̀ sì gbẹ+ láti palẹ̀ ọ̀nà mọ́ fún àwọn ọba+ láti ibi tí oòrùn ti ń yọ.*
11 Màá pe ẹyẹ aṣọdẹ wá láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+Ọkùnrin tó máa ṣe ohun tí mo pinnu*+ máa wá láti ilẹ̀ tó jìn. Mo ti sọ̀rọ̀, màá sì mú kó ṣẹ. Mo ti ní in lọ́kàn, màá sì ṣe é.+
12 Ìkẹfà da ohun tó wà nínú abọ́ rẹ̀ sínú odò ńlá Yúfírétì,+ omi rẹ̀ sì gbẹ+ láti palẹ̀ ọ̀nà mọ́ fún àwọn ọba+ láti ibi tí oòrùn ti ń yọ.*