ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 1:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Ní ọdún kìíní Kírúsì+ ọba Páṣíà, kí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu Jeremáyà+ sọ lè ṣẹ, Jèhófà ta ẹ̀mí Kírúsì ọba Páṣíà jí láti kéde ní gbogbo ìjọba rẹ̀, ó sì tún kọ ọ́ sílẹ̀+ pé:

      2 “Ohun tí Kírúsì ọba Páṣíà sọ nìyí, ‘Jèhófà Ọlọ́run ọ̀run ti fún mi ní gbogbo ìjọba ayé,+ ó sì pàṣẹ fún mi pé kí n kọ́ ilé fún òun ní Jerúsálẹ́mù,+ tó wà ní Júdà.

  • Àìsáyà 44:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ẹni tó ń sọ nípa Kírúsì+ pé, ‘Òun ni olùṣọ́ àgùntàn mi,

      Ó sì máa ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́ délẹ̀délẹ̀’;+

      Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa tún un kọ́’

      Àti nípa tẹ́ńpìlì pé, ‘Wọ́n máa fi ìpìlẹ̀ rẹ lélẹ̀.’”+

  • Àìsáyà 48:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Gbogbo yín, ẹ kóra jọ, kí ẹ sì fetí sílẹ̀.

      Ta ni nínú wọn ló kéde àwọn nǹkan yìí?

      Jèhófà nífẹ̀ẹ́ rẹ̀.+

      Ó máa ṣe ohun tó dùn mọ́ ọn nínú sí Bábílónì,+

      Apá rẹ̀ sì máa kọ lu àwọn ará Kálídíà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́