Àìsáyà 48:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbogbo yín, ẹ kóra jọ, kí ẹ sì fetí sílẹ̀. Ta ni nínú wọn ló kéde àwọn nǹkan yìí? Jèhófà nífẹ̀ẹ́ rẹ̀.+ Ó máa ṣe ohun tó dùn mọ́ ọn nínú sí Bábílónì,+Apá rẹ̀ sì máa kọ lu àwọn ará Kálídíà.+
14 Gbogbo yín, ẹ kóra jọ, kí ẹ sì fetí sílẹ̀. Ta ni nínú wọn ló kéde àwọn nǹkan yìí? Jèhófà nífẹ̀ẹ́ rẹ̀.+ Ó máa ṣe ohun tó dùn mọ́ ọn nínú sí Bábílónì,+Apá rẹ̀ sì máa kọ lu àwọn ará Kálídíà.+